Download Mp3: Tope Alabi – Funmilayo +L yrics

A Nigerian gospel singer, film music composer and actress. Tope Alabi Released a song Titled Funmilayo

Tope Alabi, also known as Ore ti o common, was born on 27 October 1970 in Lagos State, Nigeria to Pa Joseph Akinyele Obayomi and Madam Agnes Kehinde Obayomi.

Download Video, Stream and Download Mp3:

Stream and Download Mp3:

 Download Mp3

Lyrics

Olorun lo le fun ni layoEniyan ole funi layo kopeBo pe titi oo akololo a pe babaOba oke lo layo pupo lodoFunmilayoFunmilayoFunmilayo ki ire gbeyin aiye mi
Olorun lo le fun ni layoEniyan ole funi layo kopeBo pe titi oo akololo a pe babaOba oke lo layo pupo lodoFunmilayoFunmilayoFunmilayo ki ire gbeyin aiye mi
Bi emi basi wa laye ireti o pin ooAtoro ohun gbogbo lowo olorun ki kan ju oOro olorun ko ni lo laiye se layeBi omo kiniun wonma kigbe ebi kikanAwon to gbekele ki yo shale yi ri ohun ti o dara
Olorun lo le fun ni layoEniyan ole funi layo kopeBo pe titi oo akololo a pe babaOba oke lo layo pupo lodoFunmilayoFunmilayoFunmilayo ki ire gbeyin aiye mi
Bi igba ban gba ni ejiki ama ro juIgba nbo ti o gba ni olorun lo ni dedeIronu o da nkanOre lo ni suuruEti olorun ko wu wo lati gbo igbe waIgba gbo ninu Jesu lo le mu ni se ase yege
Olorun lo le fun ni layoEniyan ole funi layo kopeBo pe titi oo akololo a pe babaOba oke lo layo pupo lodoFunmilayoFunmilayoFunmilayo ki ire gbeyin aiye mi
Gbe okan le jesu apata ti kin yeMatori a ro pin ko se si eleda rePada leyin aiye ni se ni won to ni paAiye a funi ni fila a fi gba odindin ori eni l’owo eniWon ti mi a si regun ko ni wu won de ti gbe san
Olorun lo le fun ni layoEniyan ole funi layo kopeBo pe titi oo akololo a pe babaOba oke lo layo pupo lodoFunmilayoFunmilayoFunmilayo ki ire gbeyin aiye mi
Ori to mi a da de ko ma ni se a i deFunnnnnmilayoBaba fun mi layo ma je ki temi o gbe ooFunnnnnmilayoOhun to ye mi o baba ma fi dunmi o baba rere aminFunnnnnmilayoOro ti mo ba araye wi to ya gere ba mi se babaFunnnnnmilayoMo mope omo to mi a gun eseee re a tirinFunnnnnmilayo
Gbogbo a sise jeje eleri e je kalo mu suuruA fe re bo naFunnnnnmilayoT’ori koko to mi a j’ata idi re a koko gbona, uh uh uhFunnnnnmilayoE je ka se fun olorun loke loke l’owo a fun ni gbe eyen je otoFunnnnnmilayoOhun ti afe gba l’owo olorun oju ohun ti a le fun lo eh ehFunnnnnmilayoEni ba fe jeun gboingboin ati eleku gboingboin, tooto niyen
Funnnnnmilayo

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here