Ope Gold – Ajaga (Burden)

Nigerian gospel singer, praise and worship leader and a songwriter, Ope Gold releases her much anticipated single titled “AJAGA” means BURDEN in English Translation.

AJAGA is an inspired prayer song.its a revelation that is full of positive assurance. Yes we can have burden but surely it can be lifted off our shoulder and we will be free.

Stream and Download Mp3:

Download Mp3

AJAGA (BURDEN) LYRICS
Chorus
Ajaga gbo
Ajaga bo
Lorun mi o moti lo

Stanza 1
Opo lo n fokansin laye sugbon ounje iponju la fi n bowon
Awon to ye ko tara wa sin lohun won belu egan lu wa
İja ta maa ja ka to ga la n pe lajaga
Ajaga o ni se pelu owo nini
İkorita kan wa ti n doju towo lowo olowo
Ajaga ni n mekun asuunda wa ti n gbomi loju eni
Ohun to wu ko je ajaga re lo ni o o maa ja

Stanza 2
İwo eni ti a pon loju ti a n gba kiri
Olorun o ri bi eniyan laye tujuka o o maa se
Awon to ti pa o ti laye won pada bo wa ba o
Tori ojo ogo to su yi o…o maa ro sori i re
İja re ti dopin ogun si ti tan an an an
(İnterlude)

Bridge
Call:moti bo moti yege o
Resp:moti bo moti yege
Call: i am free oo mo ti bo o
Resp:motibo motiyege
Call:lowo ogun to ko mini papa mora o moti bo
Resp:moti bo moti yege
Call:we decree and declare ati bo oo ati yege

5 COMMENTS

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here