(Audio+Lyrics): Abosede Sokan (Adunjesu Ara)- Anu(Mercy)

Nigeria Worship leader, songwriter and Gospel recording artiste  has finally released the awaited single titled – “Anu ” in English Interpretation means “Mercy”


What brought about The Song.

I can boldly say,  My life have obtained the Mercy of the Lord and I will continue to obtain His Mercy daily as I live. The Mercy that has taken me far, the Mercy that brought me above condemnation, above pains, above hurts, above judgements, above limitations, above failure, above illness, above what I can ever imagine. I am always and deeply grateful for His Mercies.

Well,  it was in the middle of deep pains, hurts, condemnation, needs and above all,  REJECTION that this song was written. Always remember that weeping may endure for a night, but Joy come in the morning.

According to her;

Àánú meaning Mercy in English Language, means God Himself. I believe God is the Mercy we are talking about, whenever we need Mercy, sincerely we need God. He is rich in Mercy,  He is the only one that can show us Mercy and we will live a fruitful, fulfilled and joyful life.

Mercy that prevails over all judgement, Mercy that overlooks our sins and act on our behalf as if we’ve never sinned. I’m talking about Mercy that is renewed every morning (Lamentations 3:22-23). Mercy that speaks for us in the face of challenges, fears and problems. Mercy that gives solution without asking for it. Mercy that makes us qualifies to be children in the kingdom of Light. Oh!  Mercy!  God Himself we are talking about is the MERCY.

The beginning of Mercy, The meaning of Mercy and above all He Himself is the MERCY.

And sincerely I tell You,  living this life is about obtaining the Mercy of the Lord. We shall all obtain Mercy. Mercy is what everyone cries for daily and I hear people at the top saying “they obtained Mercy”

This song is written in Yorùbá language, Pure!

I cried for MERCY truly out of my deep, with all of me I needed it seriously. It was at the verge of dying, serious problems. But Glory to the Lord that showed Mercy.

I can boldly say I have received Mercy.

Download mp3

ANU LYRICS

Àánú! Mercy!

Ah… ah… ah…  hmm…

Chorus:

Èmi á r’áànú gbà,

Ìtàn mi á dire,

Èmiá r’áànú gbà,

Òrò mi ádayò.

Èmi á r’áànú gbà,

Ìtàn mi á dire,

Màá r’áànú gbà,

Òrò mi ájásí Ìyanu.

Solo 1:

Baba gbó ohùn mi

Nígbàtí mo ń pè

Mofi ohùn mi kígbe

Jòwó Baba gbóèbè mi

K’ómo eléran mi

Má mà se je egungun o

Kí n lè yìn ó d’ojó alé

Aláànú jùlo, Nítoríwípé,

Ánnà r’áànú gbá,

Àgàn, ó d’olómo

Éstérì r’áànú gbà

Erú lásán to d’ayaba.

Olórun tóń pa, Olórun tóń jí

Kò sohun tó lèse

Ìwo àjíndeóhun ìyè tòótó

Kò s’ohun tó lèse.

Chorus

Èmi á r’áànú gbà,

Ìtàn mi á dire,

Èmi á r’áànú gbà,

Òrò mi á dayò.

Èmi á r’áànú gbà,

Ìtàn mi á dire,

Màá r’áànú gbà,

Òrò mi á jásí Ìyanu.

Solo 2:

Ayéń wòmí mó o

Jék’ógo re bú jáde

Múgbà rere mi tètè bòwá

K’áànú fohùn jáde

Ìrètí pípéá máa s’okàn láàrè

Olú Òrun se tèmi

K’áráyétara mi yìn ó lógo

Kíàánú fohùn jáde,

Kíàánú re so ohun gbogbo di ìròrùn, kíààbò re dájú

Kí ayémi nítumò nínúàánú re

Àánú re wà f’éni gbogbo

Chorus

Èmi á r’áànú gbà,

Ìtàn mi á dire,

Èmi á r’áànú gbà,

Òrò mi á dayò.

Èmi á r’áànú gbà,

Ìtàn mi á dire,

Màá r’áànú gbà,

Òrò mi á jásí Ìyanu.

Call: K’ádùrà mi gbà,

Kórò re se nínú ayé mi

Resp: Àse

Call: Ìwo lo s’èlérí p’órò miá d’ayò nílé ayémi

Resp: Àse

Call: And according to your word, Ohun gbogbo á sisé sí dáradára mi o

Resp: Àse

Call: Ire áwámirí, màá ríre gbámú, maríbátisé o

Resp: Àse

Call: Àmín, Àse, Àse n t’èdùwà béèni kó rí

Resp: Àse

Call: Àse n’ìdáhùn Àdúrà, ònà mi tilà, Óti jásíre o

Call: Àse

Resp:Àse Àse

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here