Nigerian gospel singer and songwriter, Tope Alabi releases a new song titled Oruko Tuntun.
The sound track tagged, Oruko Tuntun was presented as track fourth track off the album that is made up of nine phenomenal records. Oruku Tuntun in Yoruba dialect means new name
Watch Video, Stream and Download Mp3:
Stream and Download Mp3:
Lyrics
Olorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa
Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyan Olorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyan Eto Olorun ni emi jeAseda f’inu f’edo f’ife da mi
O mo mi ni iri Ohun gangan Mi o ku si’bi kan, O da mi daradara Emi lamo t’owo Adaniwaye mo Eemi Aseda ni iwalaaye mi Oju ogo Re ni iriiran mi akoko Ipa lo fi se mi s’inu iya mi Ara nla owo Oga ogo ni mi Emi leniyanOlorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa
Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyan Irin ajo eda wa s’aye, esu, ota, elenini eniyan n duro Ami ibi to tele eda bo ni satani t’a le sokale lat’orun O n bu ramuramu, o n kanra, lo fi n fi’bi han eda leemoEni ba w’aye (w’aye)
Eeyan to n gb’aye (gb’aye) E ma sai bikita p’aye kun fun ibi Olorun to da wa, ko da wa tori ibi Olorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyan Ti Oluwa ni ile, ati ekun re Ohun gbogbo to da s’oke eepe lo dara Satani lo so won d’ibi Eniyan e ma se ran lowo Ma je k’an f’ibi so e loruko, ire ni’wo je o ma gbagbeOruko a maa ro ni
Jowo ma se bi alaigbon Ohun t’aa ba n je la o da Ara e gb’oruko t’awon eeyan n pe ‘ra won (oruko t’on n pe ‘ra won) E gb’oruko t’eniyan n pe ‘ra re (e gb’oruko t’on n pe ‘ra won) Oloriburuku, talaka n’on n pe ‘ra won (oruko t’on n pe ‘ra won) Agan, were, alaarun ni won n pe ‘ra won (e gb’oruko t’on n pe ‘ra won) Omugo, didinrin ni won n pe ‘ra won (oruko t’on n pe ‘ra won)Alayebaje, atoole n’on n pe ‘ra won (e gb’oruko t’on n pe ‘ra won)
Aletilapa ni won n p’omo won (oruko t’on n pe ‘ra won) Ah e o mo p’ohun t’a ba pe loruko o lagbara lori eda Ohun ti o n la koja ooo, jowo ma fi pe ‘ra e mo Enikeni to ni ‘dojuko isese kan, e ma fi pe loruko Ma f’epe san epe, maa ko oruko buburu, satani lo n je baun A ti d’ele aye na, dandan ni k’a laagun k’a to yo, sise pelu ero ire, wa a yo Awon elomiran a ni nile awon bi won o logun odun ni’gbeyawo won o ni le bimoWon a ni nile won (won kii le ko’le)
Won a ni nile awon (won kii gbo k’on to ku) Idojuko won (n’on fi n pe ‘ra won) A ni aisan to n se ohun (n lo pa ‘ya ohun) Won a tun fun loruko (alaarun idile) Won a lohun gangan (logun ebi won) Eda n f’oruko isoro (p’oriki ara re) Won a ni b’o ti n se won (n’ile awon niyen)Eda e so’ro to dara jade, ero alaafia lOlorun ni si wa
Ma f’ogun enu se ‘ra e pa Pe ‘ra e ni hun to fe je Oruko to dara lOlorun so mi Oruko to logo o lEleda n pe mi Oruko to dara ni emi n je Aseda mo mi ire Emi ako’rewaye Emi agb’ayesayo Mi o ya’gan lona kankanAisiki ola, wura oro, ara owo Aseda, lemi eniyan
Igbagbo n se pupo loro eda (alaisan ti o ni ‘gbagbo ko le gba ‘wosan) Ireti logun f’oruko tuntun (alainireti ko le kuro loju kan) Eda segun nipa oro enu re (iku ati iye wa lori ahon) Ma s’ahon d’ida fi sa ara e si wewe (wa a jere ohun to ba f’enu so) Eni to da’na s’aaro ti o gbe ‘hun le’na (o daju ko ni ‘hun se)O kan fe ya’na lasan ni, igbagbo ni yo ba ero e sise
Ja ijangbara fun oruko rere, oruko lo n ro ni Oruko to dara l’Olorun so mi Oruko to logo o l’Eleda n pe mi Oruko to dara ni emi n je Aseda mo mi ire Emi ako’rewaye Emi agb’ayesayo Mi o ya’gan lona kankan Aisiki ola, wura oro, ara owo Aseda, lemi eniyanEda to n gbe ‘nu aye, yara pada s’odo Aseda
On lo mo’di oro, On lo le yanju e F’Adaniwaye se edidi aye re, mura lati s’atunse gbogbo Ko lati je oruko t’aye n so ni, to n ba ayanmo wo ‘jakadiOre b’Olorun d’owo po o, k’aye e ko le toro
Ore b’Olorun laja, ko le j’oruko tuntun Oruko to dara lOlorun so mi Oruko to logo o lEleda n pe mi Oruko to dara ni emi n je Aseda mo mi ire Emi ako’rewaye Emi agb’ayesayo Mi o ya’gan lona kankanAisiki ola, wura oro, ara owo Aseda, lemi eniyan
Obedi-Edomu j’oruko tuntun (o j’oruko tuntun) Bartholomew j’oruko tuntun (o je oruko tuntun) Jakobu j’oruko tuntun (o j’oruko tuntun) Dafidi j’oruko tuntun (o je oruko tuntun) Maria Magdaleni j’oruko tuntun (o j’oruko tuntun) Soolu j’oruko tuntun (o je oruko tuntun) Peteru apeja j’oruko tuntun ooo (o j’oruko tuntun)At’emi nipa eje odo aguntan, mo gba ire, to je ini mi pada
Olorun to da mi w’aye o, lo ni oruko mi amutorunwa Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w’aye wa f’ogo Olorun han Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyan Emi t’a da (Emi t’a da) Laworan Olorun (Olorun) Emi eda (Emi eda) Mo ri ojurere (Ojurere) Mo loore ofe to ga julo Emi lori (Emi lori) Mi kii se iru o (Lailai) Emi t’a da (Emi t’a da) T’ewa t’ogo Olorun (Olorun)Lat’odo Aseda o, ola mi o lakawe
A ti fi oruko tuntun pe mi, emi A ti fi oruko tuntun pe mi, Amin A ti fi oruko tuntun pe mi, emi A ti fi oruko tuntun pe mi, Amin A ti fi oruko tuntun pe mi, emi A ti fi oruko tuntun pe mi, Amin .