Download Mp3: Tope Alabi – Oluwa O’tobi (Video + Lyrics)

Nigerian gospel singer, film music composer and actress Tope Alabi also known as Ore ti o common, and as Agbo Jesu release a new song titled Oluwa O’tobi.

Watch Video, Stream and Download Mp3:

Stream and Download Mp3:

Oluwa o tobi, O tobi o, O tobiKo s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobiKo s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobiOluwaOluwa o tobi, O tobi o, O tobiKo s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobiKo s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobiOluwaO tobi o, Oluwa giga lorile ede gbogboGbigbega ni O, Iwo lo logo ni orunPupopupo ni O, O koja omi okun at’osa, O ga poAjulo O o se julo
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobiKo s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobiKo s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobiOluwaOba lori aye, O tobi o ehAgba’ni loko eru, Olominira to n de’ni lorunO fi titobi gba mi lowo ogun t’apa obi mi o kaOlugbeja mi to ba mi r’ogun lai mu mi lo t’o segunAkoni ni O oOluwa o tobi, O tobi o, O tobiKo s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobiKo s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobiOluwaB’O ti tobi to oo, laanu Re tobiB’O ti tobi se o, ododo Re tobi oO tobi tife tife, Oni majemu ti kii yeAro nla to gbo jije mimu aye gbogbo alai le tanOgbon to koja ori aye gbogbo oooOluwa o tobi, O tobi o, O tobiKo s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobiKo s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobiOluwaAkoko O tobi, O tobi oOluwaIpilese ogborin o yeyeO tobiIbere Eni to f’ogbon da ohun gbogboOluwaIgbeyin ola nla, o la la ooO tobiOpin aye a’torun ko si ‘ru ReOluwaO tobi, O o se s’akawe lailai oO tobiAgbaagba merinlelogun nki O, O tobiOluwaAwon angeli won n ki O, O tobiO tobiOlorun Elijah Ireti AjanakuOluwaO ma tobi laye mi, O tobi oooO tobiIwo lo gb’orin t’O o ga, t’O gun, t’O tun feOluwaO ga, O gun, O fe, O jin, O tobi la laO tobi

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here