(Audio + Video + Lyrics): Oluwafemi Patunola – Jesu L’aabo To Daju

Nigerian Gospel music minister and songwriter, Oluwafemi Patunola declares that “Jesus is the only sure protector” in new single titled “Jesu L’aabo To Daju”.

Video directed by D&P Productions.
Stream, watch and Download Mp3

Download Mp3

LYRICS: Oluwafemi Patunola – Jesu L’aabo To Daju
Chorus:
Jesu labo to daju o
Ninu aye ese at’asan
O,jowo elese wa gba Jesu kokan re ko Le nisinmi/twice

(Verse 1)
Ojo n lo eyin Ara o
Bibo Jesu o de tan o
Akoko nlo die die
Dakun Dakun,o maa kiyesara /2x.

Chorus:
Jesu labo to daju o
Ninu aye ese at’asan
O,jowo elese wa gba Jesu kokan re ko Le nisinmi/

(Verse 2)
Ogun Nile ogun Loko
Ogun igba de igba o
A’fawon to ba gba Jesu gbo o lolugbala lo Le koyo /2x..

Chorus:
Jesu labo to daju o
Ninu aye ese at’asan
O,jowo elese wa gba Jesu kokan re ko Le nisinmi/ 2x

(Bridge)
Dakun Dakun o ojo n lo
Anti/brother teti ko gboro Oluwa
Igbala re lo se Koko, Dakun Dakun o kiyesara

Chorus:
Jesu labo to daju o
Ninu aye ese at’asan,
O,jowo elese wa gba Jesu kokan re ko Le nisinmi/ 4x

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here