(Audio + Lyrics: Damilola Ologoara – Ile Ologo (Glorious Home)

Young gospel artist, Evangelist, Songwriter and Prolific Music minister, Damilola Ologoara dished out his latest single with the inspiration of Holy Spirit titled “Ile – Ologo (Glorious Home)”

ile – Ologo is an inspirational song given to me by the inspiration of the holy spirit from John 14 : 1- 7 to bless soul’s and bring back every lost souls to God .

Stream and Download Mp3:

Download Mp3

Social Network Details :
Facebook : Damilola Ologoara
WhatsApp : 09048774356
Instagram : Ologoara 4
real
YouTube : OGIMM TV .

 

 Ile Ologo (Glorious Home) Lyrics:

Eyi ni isipaya oro ati iyanju lati oke wa fun gbogbo onigbagbo , kristieni , woli , ajinrere , pastor , oko , iyawo ati opolopo akorin emi ti ari ninu iwe johanu 14 : 1- 7 to so wipe , emi lo pese aye sile fun yin , bimo ba silo pese aye sile fun yin emi o tun padawa Emi o si mu yin lo sodo emi tikara mi , pe nibiti emi gbe want , ki eyin ki o le wa nibe pelu …. Tete se atunse ona re loni ki ojo igba , ati akoko re to rekoja lo ki o le ba jesu joba .

Olorun mi maje kin kuna mumi dodo re , majeki gbagbo mi rewesi fami mora oluwa , gbori mi soke eee edumare je kin ri o ohun gbogbo to dara ni ko sefunmi

Se wa dele 2×ce se se owo re ooo saje o dele simi

Kini moyan laayo ti o ni jen dele , kini moyan laayo tole mumi so orun nu , kini moyan laayo tole mumi padanu orun baba mi mobe o dakun gba lowo mi

1. Sowo moyan laayo ti o ni jen dele , somo moyan laayo tole mumi so orun nu , saya moyan laayo tole mumi padanu orun baba mi mobe o dakun gba lowo mi

2 . Sounje moyan laayo ti o ni jen dele , soore moyan laayo tole mumi so orun nu , sele moyan laayo tole mumi padanu orun baba mi mobe o dakun gba lowo mi

3 . Saso moyan laayo ti o ni jen dele , sebi loyan laayo tole mu o so orun nu , soko loyan laayo tole mu o padanu orun baba mi mobe o dakun gba lowo mi

4 . Sero loyan laayo ti o ni je o dele , sole loyan laayo tole mu o so orun nu , sogun moyan laayo tole mumi padanu orun baba mi mobe o dakun gba lowo mi

5 . Sese moyan laayo ti o ni jen dele , saye loyan laayo tole mu o so orun nu , sepo moyan laayo tole mumi padanu orun baba mi mobe o dakun gba lowo mi

6 . Sotin loyan laayo ti o ni je o dele , segbo loyan laayo tole mu o so orun nu , sejo moyan laayo tole mumi padanu orun baba mi mobe o dakun gba lowo mi

All Respond : Se se owo re ooo saje o dele simi

Call : Omuti nko
Woli eke
Akorin nko
Omuti
Onifekufe aye
Alagbere nko
Ole jija nko
Respond : Se se owo re ooo saje o dele simi .

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here