Mp3 + Lyrics: Kemi Ogunrinde – Oro Re

Another powerful tune titled “ORO RE” means “Your Word” in English translation from Nigerian Gospel Artiste Kemi Ogunrinde.

Stay blessed as you download “ORO RE. “

Stream and download mp3:

Download Mp3

ORO RE LYRICS:

Lead: ohun to ba so kole ye o
Ileri re wa titi lae
Oduro
Chorus:oro re ni mo diro mo
Ohun to ba so kole ye o
Ileri re wa titi lae
Oduro
Chorus:oro re ni mo diro mo
Ohun to ba so kole ye o
Ileri re wa titi lae
Oduro
Verse:oro re lati ayeraye ni
Omule kiyo yipada lailai
Okunkun lesu imole oro re atan lailai
Ifapajanu eniyan Kodi imuse oro re lowo
Botiwu Kaye koja oro re oduro
Mo mo daju ibinu eniyan kole da o duro
Oro re lopa abrahamu lerin ayo mo mo ye
Oro to so lo soba deranko o mo gba
Oro to so lomu Jesu omo re wa saye
Kiun ‘nu oro re koma ni lo lai laise
Aye le ma Sapa iyen oni korun ma la o
Aye le ma binu iyen oni kojo mayo
Igbagbo ni oni oro re ase o 2ce
Ohun to baso koleye oo
Ohun to ba tenu baba Jade koleye o
Ileri re wa lati ayeraiye ni
Oduro
Chorus:oro re ni mo diro mo
Ohun to ba so kole ye o
Ileri re wa titi lae
Oduro
Chorus:oro re ni mo diro mo
Ohun to ba so kole ye o
Ileri re wa titi lae
Oduro
Lead: Bami soro Jesu mo duro de o
Ko emi oluwa bi a ti nduro lati gbohun re
Oro enu jesu oro iye ni
Ounje iye to nfunmi lokun
Ounje atorun wa
Lead: fikun mi oluwa ebun mesesan re
Bi iri latoke jeko balemi
Ohun to ba tiso kole ye oo

Ileri re wa oduro titi laelae
Resp: ohun to ba so koleye oo
Ileri re wa titi lae oduro
Resp:ohun to ba so koleye oo
Ileri re wa titi lae oduro.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here